NÍTORÍ KORONAFAIRỌỌSI, OLÓLÙFẸ́ MÉJÌ ṢE ÌGBÉYÀWÓ TIPÁTIPÁ NÍ KADUNA {FỌTO} - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, April 28, 2020

NÍTORÍ KORONAFAIRỌỌSI, OLÓLÙFẸ́ MÉJÌ ṢE ÌGBÉYÀWÓ TIPÁTIPÁ NÍ KADUNA {FỌTO}


Ìgbéyàwó tí tọkọtaya tí ẹ ń wo yìí ṣe lópin ọ̀sẹ̀ tó kọjá yìí ló ti mú àríyànjiyàn, àti oríṣiríṣi ọ̀rọ̀ wá.

Ìpínlẹ̀ Kaduna n'ìgbéyàwó náà tí wáyé.


AWIKONKO gbọ pé ó yẹ káwọn olólùfẹ́ méjì yìí tí ṣe ìgbéyàwó wọn tipẹtipẹ, ṣùgbọ́n tí konilegbele láti dẹkùn itankalẹ àrùn Covid-19 tó ń dá àgbáyé láàmú kò jẹ. 

Ìgbà tí wọn rí í pé àwọn kò lè mú un mọ́ra mọ, lo jẹ ki wọn pinnu láti ṣe é ní bonkẹlẹ, tí wọn kò sì pe èrò pupọ pẹ̀lú àṣẹ ìjọba wí pé kò gbọ́dọ̀ sì ipejọpọ eleeyan ogún.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI