O PARI O! WỌN L'OUNJẸ T'IJỌBA APAPỌ Ń PÍN KÁÀKIRI TI BAJẸ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, April 25, 2020

O PARI O! WỌN L'OUNJẸ T'IJỌBA APAPỌ Ń PÍN KÁÀKIRI TI BAJẸ


Ko sẹni to gbọ sì ọ̀rọ̀ náà tí kò ṣe ní kàyéfì rárá lórí bíjọba ipinlẹ Ọ̀yọ́ ṣe sọ ọ di mimọ pé gbogbo irẹsi ẹgbẹsan tijọba apapọ fi ranṣẹ sì wọn lo tí bajẹ pátápátá, tí kò sì ṣeé jẹ́.

Awọn alabojuto eto ounjẹ nipinlẹ Oyo ti wọn fi lede fun awọn ara ipinlẹ Oyo.

Wọn fi lede wi pe kokoro wa ninu irẹsi naa, ti o si fihan gbangba pe awọn ounjẹ naa ti bajẹ.

Bakan naa ni wọn fikun wi pe awọn ko binu si ijọba apapọ amọ ti wọn ba ni irẹsi miran to dara awọn yoo gba lọwọ wọn.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI