ỌGBÀ Ẹ̀WỌ̀N IKOYI L'ÈKÒÓ RE O, ÌYÀ ŃLÁ LO Ń JẸ ÀWỌN ẸLẸWỌN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, April 25, 2020

ỌGBÀ Ẹ̀WỌ̀N IKOYI L'ÈKÒÓ RE O, ÌYÀ ŃLÁ LO Ń JẸ ÀWỌN ẸLẸWỌN


Ko si awitunwi kankan mọ wí pé gbogbo ọgbà ẹ̀wọ̀n káàkiri orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nílò àtúnṣe.

Ibi tí ẹ ń wo yìí ni ọgbà ẹ̀wọ̀n Ikoyi l'Èkòó, báwọn ẹlẹ́wọ̀n tó wà nibẹ ṣe ń lo ìgbésí ayé wọn re e.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI