Lànà tí í ṣe ọjọ́ Ẹti, Fraide ni ìjọba ipinlẹ Kwara tún gbé gbigba orúkọ àwọn aráàlú silẹ fún owó iṣowo gba ọ̀nà ara.
Ẹsẹ kò gbèrò nílé ẹ̀kọ́ gírámà Ansaru-Islam àti ilé ẹ̀kọ́ gírámà tilu Ilọrin nibi ti àwọn aṣojú ìjọba tí lọ ọ gba orúkọ àwọn aráàlú, pàápàá àwọn awakọ silẹ láti fún wọn lowo iṣowo.
No comments:
Post a Comment