ÈYÍ L'AWỌN OTẸẸLI TÍ GÓMÌNÀ WIKE WỌ DANÀ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, May 11, 2020

ÈYÍ L'AWỌN OTẸẸLI TÍ GÓMÌNÀ WIKE WỌ DANÀ


Ọ̀rọ̀ náà làwọn èèyàn káàkiri orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣí ń sọ títí di àsìkò yìí, ìyẹn BÍ Gómìnà Nyesom Wike ṣe wo àwọn otẹẹli méjì kan dànù n'ipinlẹ Rivers.

Ẹsun itapa-si-ofin konilegbele ni Gomina Wike fi kan àwọn aláṣẹ otẹẹli náà. 

Prudent Hotel to wá ní Alode àti Etemeteh Hotel tó wà ní Onne, n'ijọba ìbílẹ̀ Eleme làwọn otẹẹli náà tí wọn wò dànù.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI