KWARA ṢE IDANILẸKỌỌ F'ÁWỌN ÒṢÌṢẸ́ IGBIMỌ COVID-19 N'ILỌRIN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, May 15, 2020

KWARA ṢE IDANILẸKỌỌ F'ÁWỌN ÒṢÌṢẸ́ IGBIMỌ COVID-19 N'ILỌRIN


Ìjọba ipinlẹ lànà tí í ṣe Ọjọbọ, ìyẹn Tọside tún ṣe idanilẹkọọ fáwọn igbimọ tó ń dẹkun itankalẹ aarun aṣekupani Covid-19 n'ipinlẹ náà. 

Ọsibitu Ṣobi to wá ní Alagbado, Ilọrin ni idanilẹkọọ náà tí wáyé fún gbogbo àwọn òṣìṣẹ́ igbimọ máa, tó fi dé orí àwọn awakọ ọkọ̀ pajawiri {Ambulance} wọn.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI