PASUMA, GBAJUMỌ ÒṢERÉ-FUJI KÍ ỌMỌ RẸ̀, WARIZ FÚN ỌJỌ́ ÌBÍ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, May 28, 2020

PASUMA, GBAJUMỌ ÒṢERÉ-FUJI KÍ ỌMỌ RẸ̀, WARIZ FÚN ỌJỌ́ ÌBÍ


Laipẹ yìí ni gbajugbaja oṣere fuji nnì, Wasiu Alabi táwọn èèyàn mọ sì Pasuma gbé ọkàn lára àwọn ọmọ rẹ, Wariz Ayinde sórí ìkànnì ayélujára instagiraamu, níbi tó ti ń kii kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ẹ. 

Nibe lo tún ti gbàdúrà fún un, táwọn èèyàn sì ń bàa yọ wí pé Ọlọ́run tún fi ọjọ́ kún ọjọ́ tí orí ọmọ náà láyé. No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI