Bàbá àti Màmá tí ẹ ń wo yìí ni í wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣayẹyẹ ọdún mejilelọgọta tí wọn ṣe ìgbéyàwó.
Ẹ̀kọ́ ńlá leleyi jẹ́ fún gbogbo àwọn apọn àti omidan tí wọn ń fi ojú sọ́nà láti gbé ara wọn sílè gege bí t'ọkọ-t'aya.
Sùúrù, ìfẹ́ àti ìwà irẹlẹ lo lè jẹ ki ìgbéyàwó di ọjọ alẹ.
No comments:
Post a Comment