GÓMÌNÀ ABDULRAZAQ ṢE ABẸWO IBANIKẸDUN SÌ ÌDÍLÉ OKECHUKWU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, July 5, 2020

GÓMÌNÀ ABDULRAZAQ ṢE ABẸWO IBANIKẸDUN SÌ ÌDÍLÉ OKECHUKWU


Gómìnà AbdulRazaq tí ipinlẹ Kwara lọ́jọ́ Satide, Abamẹta àná tí ṣe abẹwo ibanikẹdun sì ìyàwó olóògbé Okechukwu tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tó pàdánù ẹ̀mí wọn níbi tí afara Oko-Erin tí ja lulẹ. 

F'awọn to bá rántí dáadáa, ní nǹkan bí oṣù kan àti ọjọ́ díẹ̀ sẹ́yìn ni afara náà já lulẹ lásìkò ti ojo arọọrọda kan rọ, tó sì bá pupọ dúkìá jẹ́.

Gómìnà AbdulRazaq to kọwọ-rin pẹ̀lú alaga ìgbìmọ̀ tó ń bójú tó eto àyíká, Abdulrazaq Jiddah gbàdúrà fún ìdílé náà, ó tó sì ṣèlérí pé ìjọba kò níí pá ẹnikẹ́ni tí. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI