EYI L'AWỌN ORILẸ-EDE TO NI AṢẸ LAṢẸ LATI WỌ NAIJIRIA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, August 28, 2020

EYI L'AWỌN ORILẸ-EDE TO NI AṢẸ LAṢẸ LATI WỌ NAIJIRIA


Bi awọn ileeṣẹ ọkọ ofurufu kaakiri agbaye ṣe fẹẹ bẹrẹ iṣẹ pada lorilẹ-ede Naijiria lọjọ kẹrin oṣu kẹsan an, ijọba ti gbe orukọ awọn orilẹ-ede to le wọ ilu rẹ wa sita.

 

Nibi ipade t'awọn ikọ Aarẹ lori ọrọ arun Covid-19 ṣe pẹlu awọn alaṣẹ ileeṣẹ to n bojuto ọrọ ọkọ orufuru, iyẹn Nigeria Civil Aviation Authority (NCAA) ti Balogun Musa Nuhu jẹ alakoso rẹ lọrọ naa ti waye.

 

Wọn ni awọn orukọ naa yoo jade l'ọsẹ to n bọ lẹyin t'awọn ba pari akojọpọ rẹ, nitori pe awọn gbọdọ ri i daju pe ofin naa f'ẹsẹ mulẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI