WỌN N'IKU SHEIK MAYAKI BA GOMINA ABDULRAZAQ LOJIJI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, August 25, 2020

WỌN N'IKU SHEIK MAYAKI BA GOMINA ABDULRAZAQ LOJIJIGomina AbdulRahman AbdulRazaq t'ipinlẹ Kwara ti ba gbogbo idile Khalifah Tijaniyyah, Sheikh Mayaki k'ẹdun iku eeyan wọn pataki to d'oloogbe lai duro dagbere f'aye.

Ojiji ni wọn n'iroyin iku Grand Khalifah ti Tijaniyyah n'ipinlẹ naa, Sheikh AbdulRahman Yusuf Mayaki ba Gomina AbdulRazaq.
 
Bo tilẹ jẹ pe wọn ni aisan ọjọ ogbo lo ṣeku pa Oloogbe naa, ṣugbọn asiko ti wọn l'awọn eeyan nilo rẹ gidi lo fi aye silẹ.
 
Ninu atẹjade ti gomina fi sita lati ọwọ akọwe iroyin rẹ, Rafiu Ajakaye fi sita lo ti lo ti sọ pe ipa ti oloogbe naa ko nilu Ilọrin ko ṣee gbagbe titilai.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI