Lara awọn ọjọ to yẹ ki ẹda maa gbadura fun laye,pataki ni ọjọ igbeyawo jẹ, paapaa f'awọn obi. Funra iyawo Aarẹ orilẹ-ede Naijiria, Aishat Buhari lo gbe fọto igbeyawo ọmọ rẹ, Hannan sori ikanni ayelujara rẹ.
Aso-Rock nilu Abuja ni wọn tiṣe igbeyawo naa, t'awọn eeyan jankan-jankan lorilẹ-ede yii si peju sibẹ.
Diẹ ree lara awọn fọto bi igbeyawo naa ṣe lọ si:
No comments:
Post a Comment