ÈTÒ ÀÀBÒ FẸẸ GBỌNA ARA YỌ N'IPINLẸ OGUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, October 29, 2020

ÈTÒ ÀÀBÒ FẸẸ GBỌNA ARA YỌ N'IPINLẸ OGUN


Laipẹ yìí ni igbakeji ọga ọlọpaa ẹkùn ilẹ̀ Yorùbá, Adelẹyẹ Oyebade ṣe abẹwo sí ipinlẹ Ogun láti bá gbogbo àwọn olórí eleto ààbò ṣe ìpàdé.

Gómìnà Dapọ Abiọdun àtàwọn alabaṣiṣẹpọ rẹ tó fi mọ àwọn ọba alaye àtàwọn agunbanirọ ni wọn wá níbi ìpàdé náà tó wáyé nínú ọgbà àwọn ológun, ìyẹn Arcade Ground, Oke-Mọsan n'ilu Abẹ́òkúta. 

Nígbà tó ń sọ̀rọ̀, Oyebade ni gbogbo ẹ̀bẹ̀ àwọn aráàlú láti ṣe atunto sì ìṣẹ àwọn ọlọpaa làwọn tí bẹ̀rẹ̀ iṣẹ lórí ẹ.

Gomina Abiọdun nínú ọ̀rọ̀ tiẹ̀ lo tí ṣèlérí pé ohun tí yóò bá nílò làwọn yóò pèsè láti rí í pé eto ààbò gbopọn. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI