NIKE ṢE BÀTÀ TUNTUN FUN C-RONALDO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, October 10, 2020

NIKE ṢE BÀTÀ TUNTUN FUN C-RONALDO


Obrigado Nike Football ti ṣe bàtà tuntun fún gbajugbaja agbabọọlu àgbáyé nnì, Cristiano Ronaldo, ọmọ orílẹ̀ èdè Portugal. 

Ronaldo to ń gba bọọlu fún ẹgbẹ́ agbabọọlu Juventus lo gbé ìròyìn náà síta fúnra rẹ lànà án, tó sì lòun tètè ń retí ọjọ́ tòun yóò lo bàtà náà. 

Nínú ọ̀rọ̀ rẹ síwájú sí í lo tí lòun fẹẹ fi bàtà náà ṣajọyọ iṣẹ bọọlu tòun yàn láàyò àti oriire toun tí ṣe nìdí ẹ. 
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI