ỌBASANJỌ ṢE ÌGBÉYÀWÓ ALARINRIN F'ỌMỌ RẸ̀ L'EKOO, GBOGBO AYÉ LÓ WÀ NÍBẸ̀ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, December 15, 2020

ỌBASANJỌ ṢE ÌGBÉYÀWÓ ALARINRIN F'ỌMỌ RẸ̀ L'EKOO, GBOGBO AYÉ LÓ WÀ NÍBẸ̀


Ẹsẹ̀ kò gbà èrò lópin ọ̀sẹ̀ tó kọjá yìí níbi tí ọmọ Ààrẹ orílẹ̀ èdè yìí tẹ́lẹ̀rí Olóyè Oluṣẹgun Ọbasanjọ, ìyẹn Ṣeun Ọbasanjọ tí ṣe ìgbéyàwó alarinrin pẹ̀lú olólùfẹ́ rẹ, Adeọla Ṣhonubi. 

Ìlú Èkó ni eto ìgbéyàwó náà tí wáyé, táwọn èèyàn jankan jankan tí peju pesẹ síbẹ̀. 

Díẹ̀ rèé lára àwọn fọto bí ayẹyẹ náà ṣe lọ. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI