ỌPẸ O! Ẹ WO OJÚ ÀWỌN ỌDỌ 557 TI WỌ́N LÁWỌN KÒ ṢE ẸGBẸ́ ÒKÙNKÙN MỌ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, December 19, 2020

ỌPẸ O! Ẹ WO OJÚ ÀWỌN ỌDỌ 557 TI WỌ́N LÁWỌN KÒ ṢE ẸGBẸ́ ÒKÙNKÙN MỌ


Kò dín ni 557 àwọn ọdọ tó wà nijọba ìbílẹ̀ Gokona, ìpínlẹ̀ Rivers tí wọn sọ pé ẹgbẹ́ òkùnkùn tí sú àwọn, àti pé àwọn fẹẹ ni àlàáfíà ayérayé. 

Ìsìn ayẹyẹ ńlá ni wọn ṣe fún gbogbo wọn lórí gbàgede Apostolic Field tó wà ní Bodo, ijọba ìbílẹ̀ Gokona. 

Báyìí ni eto naa ṣe lọ:

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI