ỌPẸ́ O! ỌỌNI ILÉ-IFẸ̀ FI OJÚ KAN ỌMỌ RẸ̀ FUN ÌGBÀ ÀKỌ́KỌ́ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, December 9, 2020

ỌPẸ́ O! ỌỌNI ILÉ-IFẸ̀ FI OJÚ KAN ỌMỌ RẸ̀ FUN ÌGBÀ ÀKỌ́KỌ́


Lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ mélòó kan sẹ́yìn tí wọn ṣe ikomọjade ọmọ Ọọni Ilé-Ifẹ̀, Ọmọba Tadenikawo Adesoli Aderẹmi Ogunwusi, kabiyesi tí fi ojú kan ọmọ rẹ. 

Díẹ̀ rèé lára àwọn fọ́tò:

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI