ỌDUN TUNTUN: WỌN L'AWỌN AMỌTẸKUN TUN PAAYAN MẸTA L'ỌYỌỌ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, January 8, 2021

ỌDUN TUNTUN: WỌN L'AWỌN AMỌTẸKUN TUN PAAYAN MẸTA L'ỌYỌỌ


Ruth Akanni:

Ko din ni mẹta la gbọ pe awọn eeyan t'awọn ọmọ ẹgbẹ Amọtẹkun, ẹka t'ipinlẹ Ọyọ tun ti pa bayii, gẹgẹ bi iroyin to tẹ AWIKONKO leti ṣe sọ.
 
A gbọ pe ayẹyẹ kanifa kan ti wọn ṣe lagbegbe Tapa to wa ni ijọba ibilẹ Ibarapa north, ipinlẹ Ọyọ lo da wahala nla silẹ, ti wọn si l'awọn Amọtẹkun naa ṣina ibọn bolẹ gidi.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI