KWARA: AbdulRazaq fi orúkọ àwọn kọmiṣanna tuntun ranṣẹ s'ile igbimọ aṣofin - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, May 5, 2021

KWARA: AbdulRazaq fi orúkọ àwọn kọmiṣanna tuntun ranṣẹ s'ile igbimọ aṣofin


Gomina Abdulrahman Abdulrazaq  ti ipinlẹ Kwara ti fi orúkọ àwọn márùn ùn kan to n woye lati fi wọn ṣe kọmiṣanna ranṣẹ s'ile igbimọ aṣofin ipinlẹ naa lati ṣe àgbéyẹ̀wò wọn.

Awọn orukọ naa ni wọnyi:

Deborah Aremu – Irepodun

Banigbe Remilekun Oluwatobi – Isin

Ibrahim Sulyman – Ilorin West

Saba Magret – Edu

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI