Fani-Kayọde ṣabẹwo si Ọọni Ile Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ogunwusi - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, July 17, 2021

Fani-Kayọde ṣabẹwo si Ọọni Ile Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ogunwusi


Minisita fọrọ ọkọ ori omi tẹlẹri lorileede yii, Oloye Fẹmi Fani-Kayọde ti ṣe abẹwo si Ọọni Ile Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi, Ọjaja keji.

Diẹ lara awọn fọto naa ree


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI