Nítorí ọ̀rọ Nàìjíríà, gbajúmọ̀ òṣèré tíátà bọ́ra síhòhò, ó ní Ẹ̀mí Mímọ ló rán òun - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, July 24, 2021

Nítorí ọ̀rọ Nàìjíríà, gbajúmọ̀ òṣèré tíátà bọ́ra síhòhò, ó ní Ẹ̀mí Mímọ ló rán òun


Kayeefi nla lọrọ naa ṣi n jẹ patapata fun gbogbo awọn ololufẹ gbajugbaja oṣerebinrin nni, Clarion Chukwurah Abiọla lori fọto ihoho rẹ to gbe jade laipẹ yii.

Clarion Chukwurah Abiọla lo gbe fọto ihoho ara rẹ sita lati fi kanminu lori ọrọ iṣoro to n dojukọ orilẹ-ede Naijiria.

Ori ikanni ayelujara ti Instagiramu lo gbe awọn fọto naa si, to si tun jẹ ko ye gbogbo aye wi pe oun ko gbe igbesẹ ọhun lai ni itọni Ẹmi Mimọ.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI