Ọriiri nla! Gomina AbdulRazaq fi abadofin Owo Iṣuna Eto Ẹkọ ranṣẹ sile igbimọ aṣofin - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Tuesday, July 13, 2021

Ọriiri nla! Gomina AbdulRazaq fi abadofin Owo Iṣuna Eto Ẹkọ ranṣẹ sile igbimọ aṣofin


Gomina AbdulRahman AbdulRazaq tipinlẹ Kwara ti fi abadofin owo Iṣuna Eto Ẹkọ, iyẹn, Education Trust Fund Bill, tọdun 2021 ranṣẹ si ile igbimọ aṣofin ipinlẹ naa lati le bu ọwọ lu.
 
Olori ile igbimọ aṣofin ipinlẹ naa, Yakubu Salihu Danladi lo sọ eyi di mimọ lonii, wi pe gomina ti fi abadofin naa ranṣẹ, eyi to sọ pe awọn ti n bẹrẹ agbeyẹwo rẹ.

Abadofin yii ni wọn sọ pe o wa lati le jẹ ki idagbasoke tubọ deba eto ẹkọ nipinlẹ naa, ki awọn akẹkọọ ati olukọ si le jẹ mudunmudun eto oṣelu awaarawa.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI