Ra Ilẹ̀ olówó pọ́ọ́kú tó fọkàn balẹ̀ l'Abẹ́òkúta - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, July 15, 2021

Ra Ilẹ̀ olówó pọ́ọ́kú tó fọkàn balẹ̀ l'Abẹ́òkúta


Njẹ iwọ n wa ilẹ olowo pọọku to si fi ọkan balẹ niluu Abẹokuta, ipinlẹ Ogun ati agbegbe rẹ, paapaa niluu Alabata. Ilẹ to ṣee kọ ile adagbe ati fun okoowo ṣiṣẹ wa niluu Alabata lọwọlọwọ bayii.

Ẹgbẹ ẹnu ọna abawọle keji sinu ọgba ile ẹkọ fasiti ọgbin, Federal University of Agriculture ni ilẹ naa wa. Eeka ni ilẹ ti a n sọ nipa rẹ yii.

Ko si wahala ọmọ onilẹ lori rẹ, ti ileeṣẹ wa, AWIKONKO MEDIA CHANEEL si le fọwọ rẹ sọya pe ojulowo ni.

Pupọ awọn ileeṣẹ to n ta ilẹ lo pọ lasiko yii, to si jẹ pe gbajuẹ lo pọ ju ninu wọn, ṣugbọn eyi ti a sọ nipa rẹ yii fọkan balẹ daadaa.

Iwọn bata ọgọta si ọgọfa, iyẹn 60by120ft ni ilẹ naa wa. Ilẹ to ni ontẹ mọlẹbi ni, to si ni iwe ẹri to peregede.

Fun alaye lẹkunrẹrẹ, ẹ pe ẹrọ ibanisọrọ yii, 07030303230.

Awọn nnkan mi in tiẹ tun le mọ lede oyinbo nipa ilẹ yii ni:

👉Documents:
Deed of assignment
Family Receipt

👉No omo onile wahala

👉Old measurement 60by120ft

👉It's a corner piece land

👉 The corner pieces have already been erected

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI