AbdulRazaq bu ọwọ́ lu àwọn àtúnṣe àwọn òpópónà tuntun - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, September 3, 2021

AbdulRazaq bu ọwọ́ lu àwọn àtúnṣe àwọn òpópónà tuntun


Gomina AbdulRahman AbdulRazaq tipinlẹ Kwara ti bu ọwọ lu atunṣe awọn opopona tuntun kaakiri ipinlẹ naa, lati mu irọrun ba igbokegbodo ọkọ.

Lara awọn ọna to nilo atunṣe, ti Gomina AbdulRazaq bu ọwọ lu pe ki iṣẹ bẹrẹ ni:

1. Ikorita Maraba - Ọja Ipata

2. Ikorita Chapel - Sanrab Tanke

3. Royal Shekinah - Garaaji Ọffa

4. Opopona High Court

5. Oju ọna Unity

6. Geri-Alimi - oju ọna Asa Dam

7. Challenge/Post Office

8. Oju ọna Taiwo

9. Opopona Kaduna

10. Oju ọna Oloje/Alore

11. Oju ọna Akerebiata

12. Oju ọna Alimi

13. Oju ọna Onikanga

14. Oju ọna Police

15. Oju ọna Ilofa

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI