Ajíbọ́lá, ọmọ Ta L'Ọlọhun ló n ṣe ọjọ́ ìbí lónìí - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, September 21, 2021

Ajíbọ́lá, ọmọ Ta L'Ọlọhun ló n ṣe ọjọ́ ìbí lónìí


Oni, ọjọ kọkanlelogun, oṣu kẹsan ni ayẹyẹ ọjọ ibi Ajibọla to jẹ ọmọ gbajugbaja onkọrin Musulumi nni, Hajia Amọkẹade Eebudọla, ẹni ti ọpọ awọn ololufẹ rẹ mọ si Ta L'Ọlọhun n ṣe ayẹyẹ ọjọ ibi rẹ.

Pupọ awọn ololufẹ onkọrin naa ni wọn ti n ba ọmọ rẹ yọ fun anfaani nla to ri gba lati di ọjọ oni.

Adura wa ni pe ki Ọlọhun fun Ajibọla ni ẹmi gigun ati alaafia ninu ifọkanbalẹ ati itẹlọrun. Bẹẹ si ni ki Ọlọhun jẹ ko ṣe rere tayọ awọn akẹgbẹ rẹ nile aye. Amin

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI