Ẹ wojú àwọn ògbólògbó ajínigbé márùn-ún tọ́wọ́ ọlọ́dẹ tẹ̀ ní Kogi - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, September 29, 2021

Ẹ wojú àwọn ògbólògbó ajínigbé márùn-ún tọ́wọ́ ọlọ́dẹ tẹ̀ ní Kogi


Eyi lawọn afurasi ajinigbe ti a gbọ pe ọwọ awọn ọlọdẹ ipinlẹ Kogi tẹ laipẹ yii.
 
AWIKONKO gbọ pe awọn maraarun yii ni wọn wa lara awọn to n da alaafia ilu Okene si Lọkọja, ati oju ọna Okene si Auchi nipinlẹ naa laamu.

Wọn ni loju ẹsẹ tọwọ ti tẹ wọn, ni wọn ti fa wọn le awọn agbofinro lọwọ lati tẹsiwaju iwadii lẹkunrẹrẹ lori wọn.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI