Ẹ wo ojú gbogbo àwọn ẹlẹ́wọ̀n tó sálọ lọ́gbà ẹ̀wọ̀n l'Ọ́yọ̀ọ́ - IROYIN AWIKONKO

YÀJÓ-YÀJÓ
Sunday, October 31, 2021

Ẹ wo ojú gbogbo àwọn ẹlẹ́wọ̀n tó sálọ lọ́gbà ẹ̀wọ̀n l'Ọ́yọ̀ọ́


Ileeṣẹ to n ri sọrọ abẹlẹ lorilẹ-ede yii, iyẹn Ministry of Interior ti gbe orukọ ati fọto gbogbo awọn ẹlẹwọn to na papa bora lakooko ikọlu awọn tọọgi si ọgba ẹwọn Ọyọ laipẹ yii jade.

Ọjọ kejilelogun, oṣu yii ni ikọlu naa waye, nibi ti ọpọ ẹlẹwọn ti juba ehoro.

Ileeṣẹ to n ri sọrọ abẹle wa rawọ ẹbẹ si awọn araalu lati tete fi to ileeṣẹ agbofinro leti, bi wọn ba kofiri eyikeyi ninu wọn.No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI