Ayé ò! Wọ́n tún ti rí àjaàlẹ̀ tuntun n'Íjèbú Òde o (Fọ́tò) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, November 26, 2021

Ayé ò! Wọ́n tún ti rí àjaàlẹ̀ tuntun n'Íjèbú Òde o (Fọ́tò)


Bi ẹ ṣe n ka iroyin yii, awọn agbofinro tun ti ṣawari ajaalẹ tuntun, nibi tawọn amookun ṣeka ti n pawọn eeyan nipakupa, ti wọn n fi wọn ṣẹṣo nilu Ijẹbu-Ode, ipinlẹ Ogun.

Adugbo kan ti wọn n pe ni Ogunfowora, nilu Ijẹbu-Ode la gbọ pe aṣiri ajaalẹ naa ti tu, to si n jẹ kayeefi fun pupọ awọn to n gbe lagbegbe naa.
 
Ọpọ ọkada, ati awọn eeyan ni wọn ri ninu ile ti wọn sọ di ajaalẹ naa, eyi ti igbagbọ wa wi pe wọn ti lo wọn.
 
Bẹẹ la gbọ pe ọwọ ti tẹ lara awọn oṣiṣẹ ajaalẹ ọhun.
 
Ẹkunrẹrẹ iroyin naa n bọ laipẹ, ẹ ku oju lọna.No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI