Ìjọba Mẹ̀kúnnù: Ẹgbẹ̀rún lọ́na ọgbọ̀n aráàlú tún jẹ ànfààní Owó Ìṣòwò tuntun ní Kwara o (Fọ́tò) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, November 8, 2021

Ìjọba Mẹ̀kúnnù: Ẹgbẹ̀rún lọ́na ọgbọ̀n aráàlú tún jẹ ànfààní Owó Ìṣòwò tuntun ní Kwara o (Fọ́tò)


Bo tilẹ jẹ pe lati ọdun to kọja lawọn ara ipinlẹ Kwara ti n jẹ anfaani Owo Iṣowo, Owo Arugbo ati bẹẹbẹẹlọ, ṣugbọn ipele miran tun waye yii ti jẹ ki awọn eeyan nigbagbọ pe lotitọ lawọn ti ni ijọba mẹkunnu.
 
Awọn araalu ti ko din ni ẹgbẹrun lọna ọgbọn la gbọ pe wọn tun ti jẹ anfaani Owo Iṣowo ti ijọba gbe jade bayii.
 
Gbogbo awọn to ti wa jẹ anfaani naa ti to ẹgbẹrun lọna ọgọta, ti onikaluku si n dupẹ lọwọ ijọba fun anfaani nla naa.
 
Diẹ ree lara bi eto naa ṣe lọ si.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI