Àgbáríjọ̀ àwọn obìnrin Nàìjíríà fún AbdulRazaq ni ààmì ẹ̀yẹ nlá níbi ìpàdé gbogbogbòò wọn - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, January 14, 2022

Àgbáríjọ̀ àwọn obìnrin Nàìjíríà fún AbdulRazaq ni ààmì ẹ̀yẹ nlá níbi ìpàdé gbogbogbòò wọn


Agbarijọ ẹgbẹ awọn obinrin kaakiri orileede Naijiria ti wọn pe ara wọn ni 'Progressive Women' yoo fi aami ẹyẹ nla da gomina ipinlẹ Kwara, AbdulRahman AbdulRazaq lọla, nibi ipade gbogbogboo wọn to fẹẹ waye.

Ipade gbogbogboo naa, akọkọ iru ẹ lo fẹẹ waye nilu Abuja, nibi ti Aarẹ Muhammadu Buhari, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo atawọn ọtọkulu yoo ti peju sibẹ.

Awọn ọmọ ẹgbẹ naa ti wọn wa kaakiri ipinlẹ mẹrindinlogoji to fi mo ilu FCT l'Abuja ni yoo wa nibi ipade naa, nitori pe akọkọ iru ẹ lo jẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI