Ìjọba mẹ̀kúnnù bẹ̀rẹ̀ àtúnṣe òpópónà Yebumot si Oloje - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, January 22, 2022

Ìjọba mẹ̀kúnnù bẹ̀rẹ̀ àtúnṣe òpópónà Yebumot si Oloje


Akanṣe iṣẹ ti bẹrẹ lakọtun bayii lori atunṣe opopona Yebumot - AlHikmah University - Adeta Roundabout - Oloje Road to wa nijọba ibilẹ Ilorin West.

Iroyin to tẹ wa lọwọ sọ pe ipo ti awọn opopona naa wa ko bojumu to fun igbokegbodo ọkọ, eyi to mu kijọba dide iranwọ fawọn araalu.

Latigba ti iṣẹ naa ti bẹrẹ lawọn eeyan ti n gbe oṣuba kare fun Gomina AbdulRahman AbdulRazaq.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI