Gbajumọ akọroyin, Ṣadare di akọwe ipolongo APC l'Ọyọọ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, August 30, 2022

Gbajumọ akọroyin, Ṣadare di akọwe ipolongo APC l'Ọyọọ


Ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC, ẹka t'ipinlẹ Ọyọ ti kede gbajugbaja akọroyin n'ipinlẹ naa, Ọgbẹni Wasiu Ọlawale Ṣadare, gẹgẹ bi akọwe ipolongo wọn.
 
Ọjọ Aje, Mọnde ana la gbọ pe ẹgbẹ APC bura fun Ṣadare lati bẹrẹ iṣẹ gẹgẹ bi akọwe ipolongo wọn.

A gbọ pe ọpọ awọn ọmọ ẹgbẹ ni wọn ti n rawọ ẹbẹ tipẹtipẹ si Ṣadare lati di akọwe ipolongo wọn, paapaa bi wọn ṣe n fẹ ko lo ọgbọn ati imọ rẹ fi gbe ẹgbẹ naa larugẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI