AbdulRazaq ati Ẹmir Shonga nibi ti wọn ti n sọrọ idagbasoke Kwara ninu ọgba ododo - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, December 29, 2022

AbdulRazaq ati Ẹmir Shonga nibi ti wọn ti n sọrọ idagbasoke Kwara ninu ọgba ododo


Gomina ipinlẹ Kwara, AbdulRahman AbdulRazaq ati Ẹmir ilu Shonga, Ọmọwe Haliru Yahaya lẹ n wo yii, nibi ti wọn ti n sọrọ nipa idagbasoke ati ilọsiwaju ipinlẹ naa.

Lara awọn ohun to ṣe koko ti wọn sọ nini ifọrọwerọ naa ni ọrọ eto ilera alabọde, iyẹn 'Primary Heathcare'.

Inu ọgba ododo, iyẹn Flower Garden to wa niluu Ilọrin l'awọn mejeeji ti jọ jiroro lori ọna ti ipinlẹ Kwara tun le gba lati tẹsiwaju.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI