Buhari gbaradi lati wa nibi ipolongo idibo Aarẹ ni Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, January 6, 2023

Buhari gbaradi lati wa nibi ipolongo idibo Aarẹ ni Kwara


Gbogbo eto lo ti pari fun ti eto ipolongo idibo ẹgbẹ Aarẹ ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC, eyi to fẹẹ waye n'ipinlẹ Kwara laipẹ yii.
 
Igbimọ olupolongo fun idi Aarẹ naa lo kede sita wi pe eto idibo naa fẹẹ waye, ati pe Aarẹ Muhammadu Buhari yoo wa nibi ipolongo naa fẹẹ waye niluu Kwara.

Gẹgẹ bi alakoso eto iroyin fun igbimọ naa, Festus Keyamo ṣe ṣalaye, wọn ni Aarẹ Buhari ti wa ni igbaradi lati wa nibi eto ipolongo naa.

Bẹ o ba gbagbe, Aarẹ Buhari wa nibi ti wọn ti ṣiṣọ loju ipolongo naa niluu Jos, ipinlẹ Plateau lọjọ kẹẹdogun, oṣu kọkanla, ọdun 2022.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI