Good Friday: AbdulRazaq b'awọn Kristẹni yọ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, April 8, 2023

Good Friday: AbdulRazaq b'awọn Kristẹni yọ


Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti ba gbogbo awọon ẹlẹsin Kristẹni yọ ayọ ọjọ Ẹti to dara, iyẹn Good Friday, eyi to wa nita lakoko yii.

AbdulRazaq gba awọn eeyan lamọran lati lo kọgbọn nipa iku Jesu ati ajinde Rẹ, to si ni ki wọn lo o lati maa fi ara jin fun iṣẹ tabi ipo ti wọn ba ti ba ara wọn.

Bẹẹ lo ni ki wọn maa fi ifẹ ba ara wọn lopọ, nitori pe nipa ifẹ ni ilu tabi orileede le fi ni ilọsiwaju.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI