Tinubu at'awọn olori oṣiṣẹ aabo Naijiria bẹrẹ ipade ikọkọ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, July 3, 2023

Tinubu at'awọn olori oṣiṣẹ aabo Naijiria bẹrẹ ipade ikọkọ


Lasiko ti a pari akojọpọ iroyin yii, inu ipade ikọkọ ni Aarẹ Bọla Ahmẹd Tinubu ati gbogbo awọn olori eleto aabo patapata to ṣẹṣẹ yan fun Naijiria wa.


Ile agbara orileede yii ti a mọ si Aso Rock, eyi to wa niluu Abuja ni ipade ọhun ti n waye.
 
Igba akọkọ ree ti Tinubu yoo maa ba wọn ṣepade latigba to ti yan wọn s'ipo.
 
Ẹkunrẹrẹ n bọ laipẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI