Ẹ ṣọra fun awọn ti ẹ n nifẹẹ - DJ Cuppy - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, November 20, 2023

Ẹ ṣọra fun awọn ti ẹ n nifẹẹ - DJ Cuppy


Gbajugbaja olorin takasufee nni, ọmọ Fẹmi Ọtẹdọla, Florence Ọtedọla ti ọpọ awọn ololufẹ rẹ mọ si DJ Cuppy ti gba awọn ọdọ lamọran lati iṣọra fun awọn ti wọn n nifẹẹ.
 
DJ Cuppy lo sọrọ naa lori ikanni ayelujara ti 'X' rẹ laipẹ yii.
 
O ni ọgba ẹwọn to buru julọ lati gbe lagbaye ni idile ti ko si alaafia.
 
Ninu ọrọ rẹ, o ni “ọgba ẹwọn to buru julọ lagbaye ni ile ti ko si alaafia ati ifọkanbalẹ.
 
“Ṣọra fun awọn ti ẹ fẹẹ gbe ifẹ yin le lọwọ.”

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI