ALABI OKUNMASE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, January 20, 2017

ALABI OKUNMASENje e ti gbo nipa okunrin kan ti won n pe Alabi Okunmase?

Omo bibi Isaga Orile ni Yewa, ipinle Ogun State ni.

Okunrin naa ti n gbe nilu Abeokuta ojo ti pe, ko da, ile ti ta sii, eyi to ki okunrin naa gbo ede Egba gidi gan, ko daa ju awon ti won pe ara won ni omo Egba naa lo.

Ko ka iwe pupo, nitori pe, ko mo iwe, bee ko feeli ri. Aarin meji lo wa.

Lakoko to n sise ijoba, anfaani tun si sile fun lati maa wa oko taisin (taxi) lati maa fi pawoda, ki o si maa ri owo die die lati maa fi bo ebi e.

Alabi Okunmase tera mo oko taisin e gidi leyin to feyinti nidi ise ijoba. Opo awon eeyan ni won kii fe ko maa gbe won nitori oro ti kii tete ye, to si je pe ejo lo maa n ro kaka ko koju sibi to ba n lo.

Oro kii tete ye Alabi nitori iwe ti ko ka, eyi maa n je ko pada awon ero to ba ye ko gbe lati fi pa owo wole. Ti e ba fee mo nipa Alabi Okunmase, a fi ki maa ba itan e lo lori YouTube OMOBA TV lojoojo Tosde.

Ojobo Tosde ose-ose ni fiimu awoowotan apanilerin Alabi Okunmase maa jade sita fawon eeyan lati wo.

E le rii wo lori YouTube: Omoba TV

E tun le rii wo lori;
Whatsapp: +2348032370756

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI