Minisita feto isuna lorileede Naijiria, Arabinrin Kemi Adeosun ti soro lojobo Tosde ana pe ko si nnkan tawon tun le se bi ko se pe kawon lo ya owo to to bilionu ogbon dola kawon fi le ri owo pa wole ati ki eto oro aje orileede yii fi le buyaari si.
Kemi Adeosun |
Minisita naa soro yi nilu Abuja lakoko to n
soro nibi ipade kan ti won pe ni 14th Daily Trust Dialogue, eyi ti won so akori
e ni “Beyond recession : Towards a
resilient economy”.
Bi e o ba
gbagbe, ojo kinni osu kokanla nile igbinmo asofin agba l’Abuja bu enu ate lu
owo naa nigba ti Aare Buhari fiwe lati ya owo naa ranse sawon asofin pe ki won
salaye bi won se le na owo naa, ki won si bu owo luu.
No comments:
Post a Comment