Orileede to le ni marundilaadota ni won fee sayeye odun FESTAC77 todun yi - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, January 20, 2017

Orileede to le ni marundilaadota ni won fee sayeye odun FESTAC77 todun yi


Iroyin to n lo kaakiri agbaye bayii ni ti ayeye odun Festac77 ti won ni awon orileede nile Afrika to le ni marundinlaadota ni won fee kopa lati se ayeye naa.

Gege bi AWIKONKO se gbo, ojo kinni osu kerin ni ayeye naa yoo bere kaakiri ile adulawo pelu awon eto aramanda olokan-o-jokan ti won ni won ti la sile fun ayeye naa.

Dokita Ferdinand Anikwe to je alakoso agba ajo Centre for Black Arts and Africa Civilization, CBAAC, lo soro yi lakoko to n bawon oniroyin soro niluu Ekoo lojo Aiku Sande to koja yii.

Anikwe so pe, bo tile je pea won orileede nile Afrika to fee darapo mo ayeye naa tip o, si be awon orileede bii China, USA, Japan, Canada atawon mi in ni won ti n fee darapo mo won.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI