Se looto ni Mercy Aigbe lo o sasewo nilu Oyinbo? - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, June 5, 2017

Se looto ni Mercy Aigbe lo o sasewo nilu Oyinbo?

Oko oro alufansa tawon eeyan paapaa awon ololufe awon osere tiata fi n ranse si Mercy Aigbe latojo to ti gbe foto oun ati ore e nibi ti won ti n we nihoho sori eka ayelujara Instagram ko se e fenuso.
 
Mercy Aigbe
Ohun tawon eeyan n so nipe se lawon ro pe Mercy to je omo bibi ipinle Edo lo o se itoju ara ati oju e nibi ti oko e ti luu bi eni lu bembe ni, won ko mo pe ise asewo lo loo se nibe.

Saaju akoko yi ni Mercy Aigbe ti gbe foto foto ara e nibi ti won ti n toju e sori eka ero ayelujara Instagram naa, tawon eeyan si n kaanu e pe Olorun a a fun ni alaafia to pe ye, ati pe ko se jeje.

Sugbon iyalenu lo tun je nigba ti won tun ri i ti Mercy tun gbe foto miran sita nibi to ti n we pelu aso ti won n pe ni bikini to je pe oyan ati itan e lasan lo bo, to si n rerin bi eni ti won n gbe nkan si labe.

Eyi lo bi opo awon eeyan to ri foto naa ninu, ti won si n so pe ise asewo lo loo se nilu Oyinbo, kii se pe o lo toju ara e rara. Awon kan ti e so pe ko baa le ri aaye lati se iranu lo se ba oko e ja.

Foto naa re o
Won lo ti n wa ona lati ko oko e naa sile tipetipe sugbon ti ko ri aaye, sugbon anfaani si sile lojo took e lu daku, to si fie se ba gbogbo oju e je, eyi ti won lo o gbe delu Oyin pe oun fee lo setoju oju oun.

Awon kan so pe ise asewo ti Mercy ko ri se latojo to fi fe oko e naa, ko te lorun, to si n wa ogbon arekereke lati wa gbogbo ona. Bee la tun gbo pe Mercy Aigbe ti ba okunrin kan pade nilu Oyinbo, to si n wa ona lati lo o kii.

Won ni gbogbo bo se n so fun oko e pe oun fee lo silu Oyinbo niyen ko gba a laaye lati lo nitori finrinfinrin to n ri pe o ti ni oju kan to n lo wo nibe, bee lawon kan so pe iro ni, ko ri bee.

Gbogbo bi won se n foro buruku ranse si Mercy Aigbe lojo naaa ni ko ti e ri ti won ro, ohun to n so ni pe iwofa lenu, ohun to ba wu elenu lo le fi enu e so nitori pe oun ko waye lati w ate eeyan kan lorun, ki won je koun saye oun boun se fe.


Bee lawon kan n so pe kawon to n soro buruku si Mercy Aigbe gbe enu won dake, ki won je ki Mercy se aye e, atipe kawon naa gbadura lati de ibi ti Mercy ti de laye.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI