Gomina Amosun loun yoo se iranwo fawon ijoba idagbasoke - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, November 22, 2017

Gomina Amosun loun yoo se iranwo fawon ijoba idagbasoke

Gomina ipinle Ogun, Ibikunle Amosun ti fowo soya seleri wi pe oun yoo ri daju wi pe gbogbo eto to ba to sawon ijoba ibile ati idagbasoke ti won sese da sile loun yoo fun won lati mu ki ise won yo.

Amosun soro yi lakoko to n soro nibi ipade eto isuna owo odun 2018 to waye nile igbimo asofin ipinle naa.

O so pe kii se aheso tabi iro wi pe awon ijoba idagbasoke metadinlogoji ti win da sile lodun to koja je pataki ibi ti owo ti n wole sapo ijoba ipinle naa, ati pe awon gan an lo je kawon araalu tun sunmo ijoba daadaa.

Amosun ni o di dandan kawon wa ona lati je kawon naa da duro, ki won ma si maa duro de ijoba ki won to k sohunkohun.

Bakan naa lo tun je ko ye awon eeyan wi pe latari wahala ipo oye to n sele nipinle naa, ijoba ti se tan lati bere ileejo Tribunal ti yoo maa gbo ejo won lati ba won yanju aawo to ba n sele.

Saaju akoko yi ni olori ile igbimo asofin ipinle Ogun, Onarebu Suraju Ishola Adekunbi gboriyin fawon oniroyin wi pe ipa ti won n

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI