AYE DOKITA SMITH TI BAJE O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, July 21, 2018

AYE DOKITA SMITH TI BAJE O

O ye ki n ti mu abalayi wa tipe sugbon ajalu to sele kaakiri ilu Abeokuta nipinle Ogun lojo Fraide ose to koja yi ba mi ninu je pupo, o si mu ikoro ba okan mi nigba ti mo gbo nipa isele ojo to ro fun wakati pere, to si ba opolopo dukia je, ti mo tun gbo pe ko din ni mewaa lawon oku eeyan ti agbara gbe lo ti won ko si tii pada ri, bo tile je pe won ni won si n wa awon kan.

M o fe e fi asiko yi ba awon ara ilu Abeokuta, paapaa awon ti agbara ya wo ile won to si fi dukia won sofo kedun lori ajalu naa, mo gbadura pe Olorun a gbe aanu E dide nibi ti enikookan yin ko reti aanu si, iru e ko si nii sele mo pelu ogo Olorun.

Bi mo se n ba oro Dokito Smith bo lose to koja, o see se ki e ti gbagbe, inu batiruumu (bathroom) ni mo ti jade pada sinu yara ti a ti n gbadun ara wa. Ki n ma paro, mo gbadun ara ti Dokito Smith fi abe mi da lojo naa, sugbon se ni eru ba mi nigba ti mo maa pada jade sita, ti mo ri Ogbeni yi lori beedi.

Oro buruku toun terin, sugbon ti erin ko se e rin nigba ti mo ri Dokito Smith to n gba kinni abe e mo beedi laarin iseju meta ti mo fi wa ni baluwe. Okunrin yi ko ma mu oro ibasun ni kekere e, karakara lo n gba kinni nàa mo beedi, to n laagun bi maluu to fe e ku.

'Kai! Waaat! Wot is dis' loro to tenu mi jade, se loo sare dide to n wo pakopako bi aja ta lo paa. Mo ni ki lo sele, o ni ki n ma wori, ki n ma a bo ka le tesiwaju. Sugbon sa, emi naa gboju kuro nibe, mo ba yataka bii opolo sori beedi, toun naa duro le mi lori, to n ko o funmi karakara.

Ringin toonu mi yato gedengbe lojo yi, to je pe fun bi ogun iseju ta a fi n gbadun ara wa, mi o ti e mo pe enikan n kan ilekun, afigba ti won bere sii gba ilekun naa bii pe eeyan pokunso sinu ile. Opun di dor (Open the door) ni mo gbo to je ki n tete soji, temi naa si beere pe kinni won n fe.

Won lawon fe e mo nnkan to n sele, mo ni ki won pada wa nitori pe a n sise pataki kan lowo ni. Boya le mo pe Naijiria nikan la ti maa n tiju lati so pe a n ba ara wa sun lowo, ko si nnkan to kan awon oyinbo pelu ibasun, ko sibi ti won ko ti le so pe 'wi wan tu af seesi' (we want to have sex). Mo so pe ko si nnkankan, a n gbadun ara wa ni.

Lesekese ni won yi pada, abe mi ti mo maa wo, eje ni mo ri to n jade, ko tii to ose meji ti mo pari nnkan osu mi, wahala de, Dokito Smith fi ponla abe e pe nnkan osu mi jade lai pe osu kan.

Bee, kinni abe Ogbeni yi ko lo sile rara, gbogbo abe lo n ta mi bii pe won fa ata rodo simi labe, se ni mo sare dide. Wot is dis, kai, ki lo fi si ponla e to fi n ta mi labe bayii ni mo koko beere lowo Dokita Smith, nnkan to so ni pe ki n ma binu, bawon obinrin se maa n kompuleeni naa niyen, o so pe nnkan to gbe oun kuro ni naija niyen.

Maanu yii so fun mi pe idi ti won fi n pe oun ni Dokita, nitori pe oun ko mo nipa oogun depodepo pe oun yoo gun agbere ni pe, Dokita abe awon obinrin loun, nitori toun guudu ninu ka fo idi obinrin mo. Sugbon sadede ni nnkan yi pada foun, toun ko si mo ibi ti ofa naa ti wa ba oun.

Smith so pe ko si obinrin toun ba tun abe e se ti ko pada wa a ba oun, to si je pe won maa n so ara won di Mario soun lorun ni, bee lo so pe aimoye igba loun ti loo kawo seyin ro ejo ni kootu latari awon iyawo ile toun ti ran lowo lati fun won ni kini nigba ti oko won ko ko ere ori beedi se daadaa, to si je pe kootu loun yi n ba ara oun.

O ni ko yato si pe oro ni won fi le oun kuro ni Naija, toun fi wa si Egypt, bo tile je pe kii se akoko re toun maa wa. O tun so pe se lo da bi pe oun soogun obinrin nigba toun de sibe, nitori pe bi won se n le oun kaakiri nitori kinni abe oun, bee loun n fun won, nigba to je pe ofe ni Olorun fun oun, toun ko si gbodo fi saun gege bi oruko mi.

Smith loun ko mo nnkan to sele to je pe lati bii osu mefa seyin lawon obinrin ti n sa foun, se ni won maa n so pe abe n ta awon, toun ko si mo idi e ni pato lori nnkan to n sele.

Aya mi ja pe emi naa ti ko si, buoda, o ya, e wa maa lo, o ti to. E ma ba mi laye je, nibo ni mo tii gba kinni okunrin de, ti maa wa maa fi emi ara mi wewu nitori pe mo fe e satiisifai (satisfy) eni ti mi o mo rii, ti kii se pe o ko enu ife si mi. Looto ni mi o kii fi abe mi saun, sugbon mi o le gba keeyan kan wa ba temi je, awon to nilo abe mi si po repete.

Bi Smith se fe maa dobale bebe, se ni mo pariwo lee lori, ko da a, ko tii wo sokoto tan ti won ti wa a gbe e jade sita fun mi.

E woo, ose to n bo la maa tun pade. E seun bi e se n ka iroyin Awikonko, Olorun a wa pelu yin. A o ni sofo emi, maa kan gba awa obinrin lamonran pe ka ma fi omu wa saun sawon okunrin, ki a ma baa fi aaye gba kansa (cancer).

PÍN-IN KÁÀKIRI