MOREMI ASIKO YI NI FUNSHO AMOSUN - VGN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, July 15, 2018

MOREMI ASIKO YI NI FUNSHO AMOSUN - VGN

Oga agba egbe Fijilante tijoba apapo (VGN) nipinle Ogun, Komanda Olanrewaju Nureni Adedoyin ti gboriyin fun iyawo gomina ipinle Ogun, Arabinrin Olufunsho Amosun latari iwe kan ti won fi bu ola fun lojo Satide to koja yi.


Iwe naa ti won pe akole e ni OLORI MOREMI AJASORO (QUEEN MOREMI AJASORO) la gbo pe won se ifilole e, pelu awon Akande ise to ti se.

Ninu atejade ti alukoro egbe Fijilante naa, Arabinrin Omotolani Adebodun fi ranse s'AWIKONKO laaro onii, lo ti sapejuwe iyawo Gomina Amosun, Olufunsho gege bi obinrin to ni iwa irele, iteriba, itara ohunrere ati eni to ni afokansin tooto.

Bee lo tun sapejuwe Funsho Amosun gege bi awokose laarin awon obinrin ti iwa e ko si yato si ti MOREMI AJASORO igba naa.

PÍN-IN KÁÀKIRI