AWON ADIGUNJALE TUN FI OPO EMI SOFO DANU L'EKITI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, September 20, 2018

AWON ADIGUNJALE TUN FI OPO EMI SOFO DANU L'EKITI

SERUBAWON AYEGBAJEJE

Nnkan ko rogbo niluu Igede-Ekiti, nipinle Ekiti, pelu bawon adigunjale kan se yabo won nile ifowopamo kan to je ti Union, iyen Union Bank to wa niluu naa.


Lojuese ni won ti pa awon eso aabo to wa nibe, awon osise ile ifowopamo yii atawon onibaara won naa faragba ninu e.


Leyin tawon adigunjale yii pa awon eeyan tan, ni won gbe roburobu owo lo

AWIKONKO gbo pe awon olopaa ti bere ise lati wa awon adigunjale yii kan

PÍN-IN KÁÀKIRI