EYI NI BI WON SE PAWON AKEKOO AMBROSE ALLI DANU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, September 20, 2018

EYI NI BI WON SE PAWON AKEKOO AMBROSE ALLI DANU

SERUBAWON AYEGBAJEJE

Titi dasiko yii lawon akekoo ileewe giga Ambrose Alli University, to wa niluu Ekpoma, nipinle Edo si n baraje pelu bawon omo egbe okunkun se yinbon pa awon omoleewe mewaa.


AWIKONKO gbo pe ija lo sele laarin okan ninu awon omo egbe okunkun yii pelu elomi-in, ti won si bawon pari e, sugbon omo egbe okunkun yii so pe oun ko ni i gba afi ti eni to ba oun ja yii ba ra aso mi-in foun. 
Lasiko ayeye ikekoo-jade tawon akekoo yii se laduugbo kan ti won n pe ni Judges's Quarter ni Ekpoma ni wahala yii ti sele. 

PÍN-IN KÁÀKIRI