GOMINA IPINLE KWARA TELE TI KU O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, September 22, 2018

GOMINA IPINLE KWARA TELE TI KU O

Iroyin to te AWIKONKO lowo lai pe yi je ko ye wa pe Gomina ipinle Kwara tele, Ogagun-feyinti, Femi David Lasisi Bamigboye ti jade laye, leni odun mejidinlogorin.


Omo bibi ilu Omu Aran, nijoba ibile ni Ifelodun ni Oloogbe, aburo lo je fun Ogagun Theophilus Bamigboye.

Laarin odun 1967 si odun 1975, ni Bamigboye fi se gomina ipinle Kwara. Odun 1940 ni won bi i, oun lo da eka eto eko sile nipinle Kwara, bee lo seto igbimo ti yoo ma a fun awon akekoo ileewe giga lowo ajemonu ti won n pe ni bursary.

PÍN-IN KÁÀKIRI