Opo awon to gbo nipa iroyin iku akekoo fasiti ti Michael Okpara, Louis loro naa si n se ni kayeefi titi di e bi e ti n ka iroyin.
Bo tile je pe AWIKONKO ko tii le fidi e mule nipa nnkan to sokunfa iku odomokunrin ti won lojo ori e ko tii ju odun merinlelogun lo, sibe ohun ta a gbo ni pe nitori isejoba Aare Muhammadu Buhari lo se gbemi ara e.
Bawon kan se n gbe Louis sepe pe 'akutunku e lona orun', bee lawon kan n baa kedun, tawon kan si n so pe ko ye ko ronu bo se ronu yen.
Okan lara awon ore e ti won jo wa ni eka ikekoo kan naa la gbo pe o gbe iroyin iku Louis soro ero ayelujara, tawon kan an to mon on si n so awon nnkan to n dun un lokan ko too ku.
No comments:
Post a Comment