O TAN O: WON NI BAMGBOSE JA AMOBODE JU SILE LOJIJI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, September 17, 2018

O TAN O: WON NI BAMGBOSE JA AMOBODE JU SILE LOJIJI

...O ti ba Sanwoolu lo

IGBAGBOYEMI ESUPOFO

Adari eto ipolongo fun gomina ipinle Eko, Ogbeni Akinwumi Ambode, ni Badagiri, iyen Onarebu Bamgbose Hontoyon naa ti pada leyin okunrin naa, oloselu nla yii ti ba Jide Sanwoolu toun naa dije gege bii gomina ipinle Eko labe egbe oselu APC lo.

Bamgbose, oludije funpo asoju-sofin lekun Badagiri naa wa lara awon ogunlogo omo egbe oselu APC ti won wa  ni gbongan 'City Hall' ti Sanwoolu ti fi ife re han lati dije ipo gomina Eko labe egbe oselu naa.  

Saaju akoko yii la gbo pe Bamgbose ti seto lorisirisii lati ri i pe Ambode wole leekan si i, lara e ni irin oni-milionu eeyan to pe ni 'One Milion match' fun Ambode to se ni Badagiri, a fi boro se yi, toun naa ba Sanwoolu lo bayii.

Bi nnkan se ri yii, ohun to daju saka ni pe, ewu n be loko longe fun Ambode, longe fun rare ewu ni fun gomina yii.

LATI: OJUTOLE-TOKO

PÍN-IN KÁÀKIRI