AWON EEYAN SI N SORO LORI OMO TI WON PA BABA E DANU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, November 10, 2018

AWON EEYAN SI N SORO LORI OMO TI WON PA BABA E DANU

Foto omo kekere omodun meji kan, Abul Fadl Abbas Mustapha, ti won lomo Mustapha Ingawa, to je Kopa ti wo yinbon pa nibi ikolu egbe awon elesin musulumi, Shi’ites atawon eleto aabo niluu Abuja lai pe yi.


Mustapha ta a gbo pe akeko jade leka Business Administration lo n si orileede baba e lowo niluu Abuja, asita ibon lo si ba, ko too ku.


Lojo ti won sinku e ni omo e ti lo n wo aworan e, tawon eeyan to wa nibi isnku naa si sare ya foto omo yi.


PÍN-IN KÁÀKIRI